Skip Navigation
The Endowment for Human Development
The Endowment for Human Development
Improving lifelong health one pregnancy at a time.
Donate Now Get Free Videos

Movie Theater

DNA


From The Biology of Prenatal Development.Buy Now

Script: Awọn eroja mẹrindinlaadọta ti o wa ninu saigọọti duro fun ekini ninu awọn alailẹgbẹ eto igbesi aye ọmọ enia titun. Eto pataki yi wa ninu awọn ohun kan ninu agọ ara ti a npe ni DNA. Ninu wọn ni asẹ fun idagbasoke gbogbo ara enia wa.

Awọn ohun ti a npe ni DNA yi farajọ akaba ti o lọ pọ, ti a npe ni dọbulu hẹlikisi. Lara akasọ ara akaba naa ni awọn ohun kan, ti a npe ni guanini, sitosini, adinini, ati taamini wa.

Guanini yi le darapọ mọ sitosini nikan, adinini si le darapọ mọ taamini.

All ages referenced to fertilization, not last menstrual period.
See Snapshots   |   Log in to create a playlist
Firm Hand Grasp
Firm Hand Grasp
Ready for Birth
Ready for Birth
DNA
DNA
To the Earth and Back
To the Earth and Back
Fertilization 1
Fertilization 1
Fertilization 2
Fertilization 2
Free resources and training for educators
Tell your story. Create your own pregnancy calendar.


Add a Comment

Your Name: Log In 3rd-party login: Facebook     Google     Yahoo

Comment: