Script: Awon oluwadi ti mọ bayi wipe, pupọ ninu awæn isẹ ojoojumọ ti ara agbalagba enia nse ni a ti filelẹ lati inu oyun wa – nigba pupọ, ki a to bi ni s’aye.