| ||
Script: ỌSẸ MEJE ATI ỌJỌ MẸRIN Akoko idagbasoke ki ọmọ to o w’aye ni o tubọ nye ni sii gẹgẹbi akoko ipalẹmọ, ninu eyiti ọmọ enia ti o sẹsẹ ndagbasoke njẹ ere orisirisi awọn ẹya-ara, ti o si nfi orisirisi ọgbọn han, eyiti yio lo fun wiwa laaye lẹhin ti a ba bii tan. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. |