| ||
Script: Ni ọsẹ mẹjọ ekini lẹhin idapọ ẹyin ọkunrin ati obirin, ọmọ enia ti i ndagbasoke ninu ni a npe ni ẹmubirayoo, eyiti o tumọ si “idagbasoke ninu." Akoko yi, ti a npe ni akoko ẹmubirayoo, ma nfarahan nipa fifi awọn orisirisi ẹya-ara le lẹ. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. |