| ||
Script: Laarin wakati mẹrinleloogun si wakati mejidinlaadọta lẹhin ti idapọ ti waye, a le sọ daju pe oyun ti wa nipo, nipasẹ ọkan ninu awọn ohun kan ti a npe ni homonu, eyiti orukọ rẹ njẹ "olufihan oyun inu titun”, ti o wa ninu ẹjẹ iya ọmọ. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. |