| ||
Script: Ọsẹ kẹjọ ni opin akoko ẹmubirayoo. Ni asiko yi,ọmọ inu oyun naa ti dagbasoke lati ẹyin kekere kanS̩oS̩o si ọkẹ aimọye ẹyin keekeke, eyiti yio di awọn orisirisi ẹya ara miran ti o le ni ẹgbẹrun mẹrin. Ọmọ inu oyun naa ni ida aadọrun ninu ọgọrun ẹya ara agbalagba enia. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. |