| ||
Script: Ni ara ọmọ inu oyun ti o jẹ obirin, a ti le da apo ile-ọmọ mọ, awọn ẹyin ile-ọmọ ti ko i tii dagba tan, ti a npe ni hugonia wa ninu apo ile-ọmọ naa, nibiti wọn ti npin si ọna pupọ. Awọn ẹya ara ti o wa fun ọmọ bibi yio ma farahan gẹgẹbi ẹya ara ọkunrin tabi ti obirin. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. |