Script: Bi a ba yọ ti ẹhin ati oke ori kuro, gbogbo ara ọmọ inu oyun naa ni o ma nfesi, bi a ba rọra fọwọ kan wọn.