| ||
Script: Biotilẹjẹpe ọmọ inu oyun ti le gbe ara rẹ lati ọsẹ kẹfa lẹhin ti a loyun rẹ, aboyun ma nmọ, fun igba akọkọ, wipe ọmọ inu oun ngberasọ, laarin ọsẹ kẹrinla si ikejidinloogun. Ninu asa abinibi, a npe eleyi ni gbigberasọ. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. One month = 4 weeks. |