| ||
Script: Ni ọsẹ kọkanleloogun si ikejileloogun lẹhin idapọ, ẹdọforo yio lagbara lati maa mi atẹgun sinu. Ọmọ inu oyun le gbe ile-aye nisinsinyi, nitori pe wiwa laaye ni ode apo ile-ọmọ yio S̩ee S̩e fun awọn ọmọ inu oyun kan. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. One month = 4 weeks. |