| ||
Script: Ni asiko ti o jẹ ipele kẹta ninu igba ti obirin fi nloyun, idagbasoke ọpọlọ ma nlo to idaji ninu gbogbo okun inu ti ọmọ inu oyun nlo. Ọpọlọ yio tobi sii ni iwọn ti o to ilọpo mẹrin si marun. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. One month = 4 weeks. |