| ||
Script: Ohun ti o wa ni ayika ibiti oyun inu ti dagba ma ntọka si awọn ohun ti yio fẹran lati maa jẹ lẹhin ti a ba bii. Fun apẹẹrẹ, ọmọ inu oyun ti iya rẹ jẹ ohun ti a npe ni aniisi, eyiti o fun ounjẹ kan ti a npe ni likorisi ni adun rẹ, fẹran lati maa jẹ aniisi naa lẹhin ti a bii tan. Ọmọ ikoko ti iya rẹ ko ni ohun kan se pẹlu aniisi ko fẹran ounjẹ naa rara. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. One month = 4 weeks. |