| ||
Script: Ninu apo ẹyin ni awọn yin keekeke fun ọmọ bibi, eyiti a npe ni jamu sẹẹli, wa. Ni ọsẹ karun, awọn ẹyin keekeke wọnyi yio lọ si ẹya ara ti o wa fun ọmọ bibi, eyiti o wa l’ẹgbẹ kidinrin. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. |