| ||
Script: ỌSẸ MẸFA Ni ọsẹ kẹfa, aaye ti ọpọlọ iwaju gba yio maa tobi sii ni ọna ti o ya ju awọn ẹya ọpọlọ yoku lọ. Ọmọ inu oyun naa yio bẹrẹ sii ni yi sihin sọhun. Iru yiyi sihin sọhun yi S̩e pataki lati mu ilọsiwaju ba idagbasoke iS̩an ara. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. |