| ||
Script: Apa kan lara ikun yio wu jade fun igba diẹ sinu okun ibi-ọmọ. Ilana yi, eyiti i ma S̩ẹlẹ nigbagbogbo, ni a npe ni ifun yiyọjade ni ara enia. eyi a si maa fi aaye silẹ fun awọn ẹya ara miran ninu ikun. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. |