Script: Ni ọsẹ meje ati aabọ, ohun ti a npe ni rẹtina ninu oju ni a le se akiyesi rẹ yekeyeke, awọn ipenpeju naa si ti bẹrẹ sii ni tobi sii.