| ||
Script: Ọmọ inu oyun naa ti le se ohun pupọ ni akoko yi. O le maa yi sihin sọhun pẹlu ilọra tabi irọrun, lẹẹkọkan tabi leralera, lati inu wa tabi lairotẹlẹ. Yiyi ori, nina ọrun, ati kika ọwọ ko sibi ori ma nwaye ni igba pupọ. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. |