| ||
Script: Ohun kan funfun, ti o wa fun aabo, eyiti a npe ni famisi kasehosa, yio bo gbogbo ara ọmọ inu oyun naa. Famisi yi ma ndaabobo awọ-ara kuro lọwọ awọn ohun ti npanilara, eyiti o wa ninu omira ti o wa ni apo ile-ọmọ. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. One month = 4 weeks. |