| ||
Script: OS̩U MARUN Ni ogun ọsẹ, apa kan ninu iho eti, eyiti o jẹ ẹya ara ti igbọran, yio ti tobi to ti agbalagba ninu iho eti ti o ti dagbasoke tan naa. Lati igba yi lọ, ọmọ inu oyun yio maa fesi si oriS̩iriS̩i ariwo. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. One month = 4 weeks. |