WEBVTT 00:00.000 --> 00:01.300 Awọn eroja mẹrindinlaadọta ti o wa ninu saigọọti 00:01.333 --> 00:03.700 duro fun ekini ninu awọn alailẹgbẹ 00:03.733 --> 00:07.600 eto igbesi aye ọmọ enia titun. 00:07.633 --> 00:08.1000 Eto pataki yi wa ninu 00:09.033 --> 00:12.833 awọn ohun kan ninu agọ ara ti a npe ni DNA. 00:12.867 --> 00:15.300 Ninu wọn ni asẹ fun idagbasoke 00:15.333 --> 00:17.100 gbogbo ara enia wa. 00:22.900 --> 00:25.867 Awọn ohun ti a npe ni DNA yi farajọ akaba ti o lọ pọ, 00:25.900 --> 00:30.667 ti a npe ni dọbulu hẹlikisi. 00:30.700 --> 00:33.633 Lara akasọ ara akaba naa ni awọn ohun kan, 00:33.667 --> 00:36.033 ti a npe ni guanini, 00:36.067 --> 00:43.067 sitosini, adinini, ati taamini wa. 00:43.100 --> 00:45.333 Guanini yi le darapọ mọ sitosini nikan, 00:45.367 --> 00:48.200 adinini si le darapọ mọ taamini. 00:59.233 --> 01:02.800 Ọkọọkan ninu awọn ẹyin keekeke ti a fi da enia ni o ni ọkẹ aimoye