WEBVTT 00:00.000 --> 00:02.667 Awon oluwadi ti mọ bayi wipe, pupọ ninu awæn isẹ ojoojumọ 00:02.700 --> 00:04.933 ti ara agbalagba enia nse 00:04.967 --> 00:07.233 ni a ti filelẹ lati inu oyun wa – 00:07.267 --> 00:09.733 nigba pupọ, ki a to bi ni s’aye.