WEBVTT 00:00.033 --> 00:04.400 Laarin wakati mẹrinleloogun si wakati mejidinlaadọta lẹhin ti idapọ ti waye, 00:04.433 --> 00:07.200 a le sọ daju pe oyun ti wa nipo, nipasẹ ọkan ninu awọn ohun kan ti a npe ni homonu, 00:07.233 --> 00:11.500 eyiti orukọ rẹ njẹ "olufihan oyun inu titun”, ti o wa ninu ẹjẹ iya ọmọ. 00:11.533 --> 00:14.333 Laarin ọjọ mẹta si mẹrin lẹhin idapọ ẹyin ọkunrin ati obirin,