WEBVTT 00:00.000 --> 00:04.633 Ọsẹ kẹjọ ni opin akoko ẹmubirayoo. 00:04.667 --> 00:07.233 Ni asiko yi,ọmọ inu oyun naa 00:07.267 --> 00:09.333 ti dagbasoke lati ẹyin kekere kanS̩oS̩o 00:09.367 --> 00:11.800 si ọkẹ aimọye ẹyin keekeke, 00:11.833 --> 00:17.633 eyiti yio di awọn orisirisi ẹya ara miran ti o le ni ẹgbẹrun mẹrin. 00:17.667 --> 00:19.267 Ọmọ inu oyun naa ni 00:19.300 --> 00:22.600 ida aadọrun ninu ọgọrun ẹya ara agbalagba enia.