WEBVTT 00:01.900 --> 00:03.700 Awọ ara ọmọ inu oyun naa ni asiko yi yio mọ gaara 00:03.733 --> 00:06.900 nitori pe ko nipọn pupọ. 00:06.933 --> 00:08.600 Bi awọ ara naa se nnipọn sii, 00:08.633 --> 00:11.600 ni mimọ ti o mọ yio maa dinku, 00:11.633 --> 00:14.867 eyiti o tumọ si wipe a le maa wo bi awọn ẹya inu ara 00:14.900 --> 00:18.000 ti ndagba, fun osu kan sii.