WEBVTT 00:11.233 --> 00:13.033 Laarin ọsẹ kẹrin si ikarun, 00:13.067 --> 00:15.567 ọpọlọ yio maa dagbasoke ni kiakia sii, 00:15.600 --> 00:19.133 yio si pin si ọna marun ọtọọtọ. 00:19.167 --> 00:25.167 Ori jẹ iwọn kan ninu idamẹta gbogbo ara ọmọ inu oyun naa. 00:25.200 --> 00:27.233 Ọpọlọ iwaju yio gba aaye ti o pọ fun ara rẹ, 00:27.267 --> 00:30.267 yio si di ẹya ti o tobi ju ninu ọpọlọ. 00:35.633 --> 00:38.267 Awọn iS̩ẹ ti ọpọlọ iwaju yi wa fun 00:38.300 --> 00:40.233 ni ironu, ẹkọ kikọ, 00:40.267 --> 00:43.133 iranti nkan, ọrọ sisọ, iriran, 00:43.167 --> 00:45.267 igbọran, gbigbe ọwọ tabi ẹsẹ, 00:45.300 --> 00:47.000 ati yiyanju ọran ti o S̩oro.