WEBVTT 00:00.000 --> 00:02.033 Ninu apo ẹyin ni awọn yin keekeke fun ọmọ bibi, 00:02.067 --> 00:05.500 eyiti a npe ni jamu sẹẹli, wa. 00:05.533 --> 00:07.067 Ni ọsẹ karun, 00:07.100 --> 00:09.000 awọn ẹyin keekeke wọnyi yio lọ 00:09.033 --> 00:10.633 si ẹya ara ti o wa fun ọmọ bibi, 00:10.667 --> 00:13.167 eyiti o wa l’ẹgbẹ kidinrin.