WEBVTT 00:00.000 --> 00:02.633 Ọkọọkan ninu awọn ẹyin keekeke ti a fi da enia ni o ni ọkẹ aimoye 00:02.667 --> 00:05.133 awọn ohun ti a darukọ loke wọnyi ninu. 00:05.167 --> 00:09.500 DNA inu ọkan ninu awọn ẹyin keekeke ti a fi da enia yi ni oriS̩iriS̩i alaye ninu, 00:09.533 --> 00:12.100 ti o jẹ wipe, bi a ba fẹ kọ wọn silẹ ni ọrọ, 00:12.133 --> 00:14.867 lẹta ekini ninu ọkọọkan awọn ohun ti a darukọ wọnyi 00:14.900 --> 00:19.500 yio gba oju ewe iwe ti o to miliọnu kan ati aabọ! 00:19.533 --> 00:21.967 Bi a ba gbe wọn si ẹgbẹ ara wọn, 00:21.1000 --> 00:26.867 DNA inu okansoso ninu awọn ẹyin keekeke wọnyi yio gun to iwọn ẹsẹ mẹta ati diẹ 00:26.900 --> 00:28.767 tabi mita kan.