WEBVTT 00:01.067 --> 00:04.700 Ni ọsẹ kẹfa ati aabọ, awọn igunpa ọwọ yio ti yanju, 00:04.733 --> 00:06.800 aami ori ika ọwọ yio ti maa han, 00:06.833 --> 00:09.333 enia si le maa wo ọwọ naa bi o ti nmi.