WEBVTT 00:00.000 --> 00:02.033 Dida egungun ara, eyiti a npe ni osifikesan 00:02.067 --> 00:03.400 yio bẹrẹ lati ibi egungun ejika, 00:03.433 --> 00:06.533 eyiti a npe ni egungun kọla, 00:06.567 --> 00:09.267 ati egungun oke ati isalẹ agbọn ẹnu.