WEBVTT 00:00.000 --> 00:01.467 Bi a ba le tu gbogbo DNA yi palẹ 00:01.500 --> 00:04.533 ninu ọkẹ aimọye ẹyin keekeke ti o wa ni ara agbalagba enia, 00:04.567 --> 00:09.300 yio gun to iwọn mẹtalelọgọta biliọnu maili. 00:09.333 --> 00:12.833 Gigun rẹ yi to ki a rin irin ajo lati aye lọ si ibiti oorun wa, ati ki a pada 00:12.867 --> 00:15.633 ni ọọdun igba, o le ni ogoji.