WEBVTT 00:00.000 --> 00:07.967 ỌSẸ MẸJỌ 00:11.167 --> 00:13.833 Ni ọsẹ kẹjọ, ọpọlọ ti dagbasoke daada, 00:13.867 --> 00:19.667 o si jẹ iwọn idaji ninu gbogbo ara. 00:19.700 --> 00:22.667 Idagbasoke yio maa tẹsiwaju ni kiakia.