WEBVTT 00:00.000 --> 00:06.033 Ni ọsẹ kẹjọ, iwọn ida marundinlọgọrin ninu ọgọrun ọmọ inu oyun ni maa lo ọwọ ọtun. 00:06.067 --> 00:08.000 Awọn yoku ni a le pin si 00:08.033 --> 00:12.367 awọn ti yio lo ọwọ osi, ati awọn ti yio lo mejeeji. 00:12.567 --> 00:19.067 Eyi ni o kọkọ fi iwa lilo ọwọ ọtun tabi ọwọ osi han.