WEBVTT 00:00.000 --> 00:01.933 Iwe ẹkọ nipa ilera awọn ọmọde se apejuwe “yiyirapada ọmọde” 00:01.967 --> 00:07.933 gẹgẹbi iS̩ẹlẹ tii maa waye laarin ọsẹ kẹwa si ogun ọsẹ lẹhin ibimọ. 00:07.967 --> 00:10.633 sugbọn iru iwa ti o yanilẹnu yi 00:10.667 --> 00:13.700 ma nsaba waye nibiti agbara ti nfa ohun gbogbo walẹ ko ti pọ, 00:13.733 --> 00:19.633 ninu apo ile-ọmọ, eyiti omi kun inu rẹ. 00:19.667 --> 00:21.733 Aini agbara ti o pọ to 00:21.767 --> 00:23.800 lati bori agbara ti nfa ohun gbogbo walẹ yi 00:23.833 --> 00:27.533 ni ayika ti o yatọ si ti ile-ọmọ, ni ko le jẹki ọmọ ti a sẹsẹ bi le yi ara rẹ pada.