WEBVTT 00:00.000 --> 00:01.233 Ọmọ inu oyun naa ti le se ohun pupọ 00:01.267 --> 00:04.967 ni akoko yi. 00:05.000 --> 00:07.500 O le maa yi sihin sọhun pẹlu ilọra tabi irọrun, 00:07.700 --> 00:09.467 lẹẹkọkan tabi leralera, 00:09.500 --> 00:12.500 lati inu wa tabi lairotẹlẹ. 00:12.700 --> 00:16.467 Yiyi ori, nina ọrun, ati kika ọwọ ko sibi ori 00:16.500 --> 00:20.100 ma nwaye ni igba pupọ.