WEBVTT 00:00.000 --> 00:02.400 O fẹrẹ to wakati mẹrinleloogun si ọgbọn wakati lẹhin idapọ ẹyin ọkunrin ati obirin, 00:02.433 --> 00:05.533 ki saigọọti to pari pinpin si meji rẹ akọkọ. 00:05.567 --> 00:07.400 Nipasẹ ọna ti a npe ni maitosisi, 00:07.433 --> 00:14.067 ẹyin kan yio pin si meji,meji yio pin si mẹrin, ati bẹẹbẹẹ lọ.