WEBVTT 00:00.000 --> 00:00.433 Lẹhin ọsẹ kan, 00:00.467 --> 00:02.333 ẹyin keekeke ti o wa lara akojọpọ ẹyin inu 00:02.367 --> 00:03.867 yio di awọ fẹlẹfẹlẹ meji ti a npe ni 00:03.900 --> 00:05.367 aipobilasiti 00:05.400 --> 00:09.367 ati ẹpibilasiti. 00:09.400 --> 00:10.1000 Aipobilasiti yi ni yio di ohun ti a npe ni 00:11.033 --> 00:12.433 apo ẹyin, 00:12.467 --> 00:14.767 eyiti o jẹ ọkan lara awọn ẹya ara, nipasẹ eyiti 00:14.800 --> 00:16.467 iya yio maa gba fun 00:16.500 --> 00:19.333 oyun inu rẹ l’ounjẹ. 00:19.367 --> 00:21.367 Ẹyin keekeke lati ara ẹpibilasiti yio di 00:21.400 --> 00:23.433 awọ fẹlẹfẹlẹ kan ti a npe ni aminiọnu, 00:23.467 --> 00:24.933 ninu eyiti ọmọ inu oyun ti a S̩ẹS̩ẹ ni, 00:24.967 --> 00:26.167 ati ọmọ inu oyun ti o ti le ni ọsẹ mẹjọ 00:26.200 --> 00:28.500 yio ti maa dagbasoke titi di akoko ibimọ. 00:28.533 --> 00:31.200 Lẹhin ọsẹ meji ati aabọ, 00:31.233 --> 00:32.800 ẹpibilasiti yio ti di 00:32.833 --> 00:34.533 oriS̩i ẹya ara mẹta, 00:34.733 --> 00:35.900 tabi awọ fẹlẹfẹlẹ, 00:35.933 --> 00:39.833 ti a npe ni ẹkitodaamu, 00:39.867 --> 00:44.800 ẹndodaamu, 00:44.833 --> 00:48.767 ati mẹsodaamu. 00:48.800 --> 00:50.033 Ekitodaamu yio di 00:50.067 --> 00:51.467 awọn oriS̩iriS̩i ẹya ara 00:51.500 --> 00:53.767 bii ọpọlọ, 00:53.800 --> 00:56.333 ọpa-ẹhin, 00:56.367 --> 00:58.533 iS̩an-ara, 00:58.733 --> 01:00.533 awọ-ara, 01:00.733 --> 01:03.333 eekanna, 01:03.367 --> 01:07.233 ati irun. 01:07.267 --> 01:11.867 Ẹndodaamu yio di awọ ti a fi tẹ inu ẹya ara ti atẹgun ngba lara enia 01:11.900 --> 01:14.300 ati ti inu ẹya ara ti ounjẹ ngba, 01:14.333 --> 01:16.867 yio si tun di lara oriS̩iriS̩i awọn ẹya ara miran 01:16.900 --> 01:19.367 bii ẹdọ 01:19.400 --> 01:22.1000 ati ẹya ara ti oronro ngbe inu rẹ. 01:23.033 --> 01:26.767 Mẹsodaamu yio di ọkan, 01:26.800 --> 01:29.100 kidinrin, 01:29.133 --> 01:31.533 egungun, 01:31.733 --> 01:33.867 kerekere, 01:33.900 --> 01:36.100 iS̩an, 01:36.133 --> 01:37.767 ẹjẹ, 01:37.800 --> 01:41.200 ati awọn ẹya miran.