| ||
Script: OS̩U MẸSAN Ọmọ inu oyun yio mu ki irọbi bẹrẹ nigbati ohun kan ti a npe ni ẹsitirogini ba njade lara rẹ, ti o si bẹrẹ ayipada rẹ lati ọmọ inu oyun si ọmọ ikoko. Rirọbi ma nwaye pẹlu sisunki ile-ọmọ, eyiti yio fa bibi ọmọ. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. One month = 4 weeks. |