| ||
Script: Ọkan enia ma nmi niwọn igba mẹtalelaadọfa laarin isẹju kan. Sakiyesi bi awọ ara ọkan naa ti nyipada bi ẹjẹ ti nwọ inu awọn iho rẹ, ti o si njade. Ọkan enia maa nmi niwọn igba mẹrinlelaadọta miliọnu ki a to bi ni, ati niwọn igba miliọnu mẹta, o le diẹ ni igbesi aye enia ti o pe ọmọ ọgọrin ọdun. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. |