| ||
|
Script: Lati igbati ọsẹ mẹjọ ba kọja, titi di opin iloyun, "ọmọ enia ti ndagbasoke ninu yi ni a npe ni fitọọsi,” itumọ eyiti nse "ọmọ ti a ko i tii bi." Ni akoko yi, eyiti a npe ni akoko fitọọsi, gbogbo ẹya-ara ọmọ naa yio dagbasoke sii, wọn yio si maa sisẹ. | ||
| All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. |