| ||
Script: Bi a ba nsọrọ nipa awọn ohun alaaye, "idagbasoke enia bẹrẹ lati igbati idapọ ba w’aye laarin ẹyin ọkunrin ati obirin," nigbati ọkunrin ati obirin ba da mẹtaleloogun ninu awọn eroja ti o wa ninu ẹya-ara wọn pọ, nipasẹ idapọ ẹya-ara ti o wa fun ọmọ bibi. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. |