Script: Lẹhin ọsẹ mẹta ọpọlọ yio pin si ọna mẹta ọtọọtọ ti a npe ni ọpọlọ iwaju, ọpọlọ aarin, ati ọpọlọ ẹhin.
Idagbasoke awọn ẹya ara ti ngbe ẹjẹ ati ounjẹ kaakiri ara ti bẹrẹ pẹlu.