Script: Ni ọsẹ kẹfa ati aabọ, awọn igunpa ọwọ yio ti yanju, aami ori ika ọwọ yio ti maa han, enia si le maa wo ọwọ naa bi o ti nmi.