| ||
|
Script: Ni ọsẹ kẹjọ, iwọn ida marundinlọgọrin ninu ọgọrun ọmọ inu oyun ni maa lo ọwọ ọtun. Awọn yoku ni a le pin si awọn ti yio lo ọwọ osi, ati awọn ti yio lo mejeeji. Eyi ni o kọkọ fi iwa lilo ọwọ ọtun tabi ọwọ osi han. | ||
| All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. |