Script: Bi a ba fọwọ kan-an, ọmọ inu oyun naa yio yara di oju rẹ, yio gbe agbọn rẹ, yio ma wa ohun ti o le dimu, yio si ma na ika ẹsẹ rẹ.