| ||
Script: Ọmọ inu oyun naa le di nkan mu, o le mi ori rẹ siwaju ati sẹhin, o le la ẹnu rẹ, o le gbe ahọn rẹ, o le poS̩e, osi le na. Isan-ara ti o wa ni oju, atẹlẹwọ, ati atẹlẹsẹ ma nmọ ọ lara bi a ba fi ọwọ kan wọn. “Bi a ba rọra fi ọwọ kan gigise,” ọmọ inu oyun yio rọ ibadi rẹ ati orunkun rẹ yio si lẹ ọmọ-ika ẹsẹ rẹ pọ | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. |