| ||
Script: OS̩U MẸTA SI ỌSẸ MỌKANLA ATI ỌJỌ MẸTA Biotilẹjẹpe ẹya akọ tabi abo ma nfarahan lati igbati idapọ ẹyin ọkọ ati aya ba ti waye, awọn ẹya ara ti o wa fun ọmọ bibi ni a le damọ bayi, gẹgẹ bi ẹya ti akọ tabi ti abo. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. |