Script: Ni ọsẹ kẹẹdogun, awọn ohun tii ma ndi ẹjẹ lara enia yio farahan, wọn a si maa pọ sii ninu ọra inu egungun. Ibiyi ni a o ti sẹda pupọ ninu ẹjẹ ara ọmọ enia.