| ||
Script: Ni ọsẹ kẹrindinlọgbọn, oju yio yọ omije. Ẹyin oju ma nfesi si imọlẹ lati bi ọsẹ kẹtadinlọgọn. Ifesi yi ma nse ilana bi imọlẹ ti ntan sinu ẹyin oju, ni gbogbo ọjọ ti ọmọ naa yio gbe laye. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. One month = 4 weeks. |