| ||
Script: Ni oS̩u mẹrin ti o kẹhin ninu oyun, ọmọ inu oyun ma nhu awọn iwa kan letoleto, laarin eyiti o ma nni akoko isinmi. Awọn iwa wọnyi nfihan bi isẹ ti ọpọlọ ati awọn ka rẹ nS̩e ti lagbara to. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. One month = 4 weeks. |