| ||
Script: OS̩U MẸJỌ Nigbati o ba to ọsẹ mejilelọgbọn, awọn iho, tabi apo atẹgun, yio bẹrẹ sii waye ninu ẹdọforo. Wọn yio maa dagba sii titi di igba ti ọmọ naa yio pe ọmọ ọdun mẹjọ. | ||
All ages referenced to fertilization, not last menstrual period. One month = 4 weeks. |